Eweko ti Yoruba n pe ni Eti Erin, ti oyinbo n pe ni Aloe vera, gbajumọ pupọ kaakiri agbaye, nitori iwulo rẹ. Bi wọn ṣe n lo o fun iṣaraloge lo tun wulo fun ilera. Oje rẹ to maa n yọ̀, wulọ pupọ fun ...
Gbajugbaja oṣere tiata, Tayo Amokade, ti ọpọ eeyan mọ si Ijebu sọrọ lori iṣẹ tiata ati idile rẹ lapapọ ninu ifọrọwanilẹnuwo ti o ṣe pẹlu BBC Yoruba. Ijebu ni ''kafinta ni baba mi, obi ni iya mi n ta ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results